37 Àwọn kan ninu wọn ń sọ pé, “Ọkunrin yìí tí ó la ojú afọ́jú, ǹjẹ́ kò lè ṣe é kí ọkunrin yìí má fi kú?”
Ka pipe ipin Johanu 11
Wo Johanu 11:37 ni o tọ