Johanu 11:45 BM

45 Ọpọlọpọ ninu àwọn Juu tí ó wá sọ́dọ̀ Maria gba Jesu gbọ́ nígbà tí wọ́n rí ohun tí ó ṣe.

Ka pipe ipin Johanu 11

Wo Johanu 11:45 ni o tọ