Johanu 12:11 BM

11 nítorí pé nítorí rẹ̀ ni ọpọlọpọ àwọn Juu ṣe ń kúrò ninu ẹ̀sìn wọn, tí wọn ń gba Jesu gbọ́.

Ka pipe ipin Johanu 12

Wo Johanu 12:11 ni o tọ