Johanu 13:11 BM

11 Ó ti mọ ẹni tí yóo fi òun lé àwọn ọ̀tá lọ́wọ́; nítorí náà ni ó ṣe sọ pé, “Kì í ṣe gbogbo yín ni ó mọ́.”

Ka pipe ipin Johanu 13

Wo Johanu 13:11 ni o tọ