Johanu 13:2 BM

2 Bí wọ́n ti ń jẹun, Èṣù ti fi sí Judasi ọmọ Simoni Iskariotu lọ́kàn láti fi Jesu lé àwọn ọ̀tá lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Johanu 13

Wo Johanu 13:2 ni o tọ