Johanu 15:22 BM

22 Bí n kò bá wá láti bá wọn sọ̀rọ̀, wọn kì bá tí ní ẹ̀ṣẹ̀. Ṣugbọn nisinsinyii, wọn kò ní àwáwí fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Johanu 15

Wo Johanu 15:22 ni o tọ