Johanu 18:15 BM

15 Ṣugbọn Simoni Peteru ń tẹ̀lé Jesu pẹlu ọ̀kan ninu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn. Ọmọ-ẹ̀yìn keji yìí jẹ́ ẹni tí Olórí Alufaa mọ̀.

Ka pipe ipin Johanu 18

Wo Johanu 18:15 ni o tọ