Johanu 18:26 BM

26 Ọ̀kan ninu àwọn ẹrú Olórí Alufaa, tí ó jẹ́ ẹbí ẹni tí Peteru gé létí bi Peteru pé, “Ǹjẹ́ n kò rí ọ ninu ọgbà pẹlu rẹ̀?”

Ka pipe ipin Johanu 18

Wo Johanu 18:26 ni o tọ