Johanu 18:38 BM

38 Pilatu bi í pé, “Kí ni òtítọ́?”Nígbà tí ó ti sọ báyìí tán, ó tún jáde lọ sọ́dọ̀ àwọn Juu, ó sọ fún wọn pé, “Èmi kò rí ẹ̀bi kankan tí ó jẹ.

Ka pipe ipin Johanu 18

Wo Johanu 18:38 ni o tọ