Johanu 19:32 BM

32 Àwọn ọmọ-ogun bá lọ, wọ́n dá ekinni-keji àwọn tí wọ́n kàn mọ́ agbelebu pẹlu Jesu lójúgun.

Ka pipe ipin Johanu 19

Wo Johanu 19:32 ni o tọ