Johanu 19:7 BM

7 Àwọn Juu dá a lóhùn pé, “A ní òfin kan, nípa òfin náà, ikú ni ó tọ́ sí i, nítorí ó fi ara rẹ̀ ṣe Ọmọ Ọlọrun.”

Ka pipe ipin Johanu 19

Wo Johanu 19:7 ni o tọ