Johanu 2:9 BM

9 Nígbà tí alága àsè tọ́ omi tí ó di ọtí wò, láì mọ ibi tí ó ti wá, (bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn iranṣẹ tí ó bu omi náà mọ̀), alága àsè pe ọkọ iyawo.

Ka pipe ipin Johanu 2

Wo Johanu 2:9 ni o tọ