Johanu 20:11 BM

11 Ṣugbọn Maria dúró lóde lẹ́bàá ibojì, ó ń sunkún. Bí ó ti ń sunkún, ó bẹ̀rẹ̀ ó yọjú wo inú ibojì,

Ka pipe ipin Johanu 20

Wo Johanu 20:11 ni o tọ