Johanu 20:18 BM

18 Maria Magidaleni bá lọ sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn pé, “Mo ti rí Oluwa!” Ó bá sọ ohun tí Jesu sọ fún un fún wọn.

Ka pipe ipin Johanu 20

Wo Johanu 20:18 ni o tọ