Johanu 20:4 BM

4 Àwọn mejeeji bẹ̀rẹ̀ sí sáré; ṣugbọn ọmọ-ẹ̀yìn keji ya Peteru sílẹ̀, òun ni ó kọ́ dé ibojì.

Ka pipe ipin Johanu 20

Wo Johanu 20:4 ni o tọ