Johanu 21:9 BM

9 Nígbà tí wọ́n gúnlẹ̀, wọ́n rí ẹja lórí iná eléèédú, wọ́n tún rí burẹdi.

Ka pipe ipin Johanu 21

Wo Johanu 21:9 ni o tọ