Johanu 3:4 BM

4 Nikodemu bi í pé, “Báwo ni a ti ṣe lè tún ẹni tí ó ti di àgbàlagbà bí? Kò sá tún lè pada wọ inú ìyá rẹ̀ lẹẹkeji kí á wá tún un bí!”

Ka pipe ipin Johanu 3

Wo Johanu 3:4 ni o tọ