Johanu 4:20 BM

20 Ní orí òkè tí ó wà lọ́hùn-ún yìí ni àwọn baba wa ń sin Ọlọrun, ṣugbọn ẹ̀yin wí pé Jerusalẹmu ni ibi tí a níláti máa sìn ín.”

Ka pipe ipin Johanu 4

Wo Johanu 4:20 ni o tọ