Johanu 4:3 BM

3 Nígbà tí Jesu mọ̀ pé àwọn Farisi ti gbọ́ ìròyìn yìí, ó kúrò ní Judia, ó tún pada lọ sí Galili.

Ka pipe ipin Johanu 4

Wo Johanu 4:3 ni o tọ