Johanu 4:38 BM

38 Mo ran yín láti kórè níbi tí ẹ kò ti ṣiṣẹ́ ọ̀gbìn. Àwọn ẹnìkan ti ṣiṣẹ́, ẹ̀yin wá ń jèrè iṣẹ́ wọn.”

Ka pipe ipin Johanu 4

Wo Johanu 4:38 ni o tọ