Johanu 4:40 BM

40 Nígbà tí àwọn ará Samaria dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, wọ́n bẹ̀ ẹ́ kí ó dúró lọ́dọ̀ wọn. Ó bá dúró níbẹ̀ fún ọjọ́ meji.

Ka pipe ipin Johanu 4

Wo Johanu 4:40 ni o tọ