Johanu 5:17 BM

17 Ṣugbọn Jesu dá wọn lóhùn pé, “Baba mi ń ṣiṣẹ́ títí di ìsinsìnyìí, èmi náà sì ń ṣiṣẹ́.”

Ka pipe ipin Johanu 5

Wo Johanu 5:17 ni o tọ