Johanu 5:21 BM

21 Nítorí bí Baba ti ń jí àwọn òkú dìde, tí ó ń sọ wọ́n di alààyè, bẹ́ẹ̀ gan-an ni, ẹnikẹ́ni tí Ọmọ bá fẹ́ ni ó ń sọ di alààyè.

Ka pipe ipin Johanu 5

Wo Johanu 5:21 ni o tọ