Johanu 5:23 BM

23 kí gbogbo eniyan lè bu ọlá fún Ọmọ bí wọ́n ti ń bu ọlá fún Baba. Ẹni tí kò bá bu ọlá fún Ọmọ kò bu ọlá fún Baba tí ó rán an wá sí ayé.

Ka pipe ipin Johanu 5

Wo Johanu 5:23 ni o tọ