Johanu 6:14 BM

14 Nígbà tí àwọn eniyan rí iṣẹ́ ìyanu tí ó ṣe, wọ́n ní, “Dájúdájú, eléyìí ni wolii Ọlọrun náà tí ó ń bọ̀ wá sí ayé.”

Ka pipe ipin Johanu 6

Wo Johanu 6:14 ni o tọ