Johanu 6:17 BM

17 wọ́n wọ ọkọ̀, wọ́n ń lọ sí Kapanaumu ní òdìkejì òkun. Òkùnkùn ti ṣú ṣugbọn Jesu kò ì tíì dé ọ̀dọ̀ wọn.

Ka pipe ipin Johanu 6

Wo Johanu 6:17 ni o tọ