Johanu 7:1 BM

1 Lẹ́yìn èyí, Jesu ń lọ káàkiri ní ilẹ̀ Galili nítorí kò fẹ́ máa káàkiri ilẹ̀ Judia mọ́, nítorí àwọn Juu ń wá ọ̀nà láti pa á.

Ka pipe ipin Johanu 7

Wo Johanu 7:1 ni o tọ