Johanu 7:41 BM

41 Àwọn mìíràn ń sọ pé, “Òun ni Mesaya.”Ṣugbọn àwọn mìíràn ń sọ pé, “Báwo ni Mesaya ti ṣe lè wá láti Galili?

Ka pipe ipin Johanu 7

Wo Johanu 7:41 ni o tọ