Johanu 7:52 BM

52 Wọ́n dá a lóhùn pé, “Àbí ará Galili ni ìwọ náà? Lọ wádìí kí o rí i pé wolii kankan kò lè ti Galili wá!”

Ka pipe ipin Johanu 7

Wo Johanu 7:52 ni o tọ