Johanu 8:37 BM

37 Mo mọ̀ pé ìran Abrahamu ni yín, sibẹ ẹ̀ ń wá ọ̀nà láti pa mí, nítorí ọ̀rọ̀ mi kò rí àyè ninu yín.

Ka pipe ipin Johanu 8

Wo Johanu 8:37 ni o tọ