Johanu 8:59 BM

59 Wọ́n bá ṣa òkúta, wọ́n fẹ́ sọ ọ́ lù ú, ṣugbọn ó fi ara pamọ́, ó bá kúrò ninu Tẹmpili.

Ka pipe ipin Johanu 8

Wo Johanu 8:59 ni o tọ