Johanu 9:15 BM

15 Àwọn Farisi tún bi ọkunrin náà bí ó ti ṣe ríran. Ó sọ fún wọn pé, “Ó lẹ amọ̀ mọ́ mi lójú, mo lọ bọ́jú, mo bá ríran.”

Ka pipe ipin Johanu 9

Wo Johanu 9:15 ni o tọ