Johanu 9:17 BM

17 Wọ́n tún bi ọkunrin afọ́jú náà pé, “Kí ni ìwọ alára sọ nípa lílà tí ó là ọ́ lójú?”Ọkunrin náà ní, “Wolii ni.”

Ka pipe ipin Johanu 9

Wo Johanu 9:17 ni o tọ