Johanu 9:2 BM

2 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ bi í pé, “Olùkọ́ni, ta ni ó dẹ́ṣẹ̀, ọkunrin yìí ni, tabi àwọn òbí rẹ̀, tí wọ́n fi bí i ní afọ́jú?”

Ka pipe ipin Johanu 9

Wo Johanu 9:2 ni o tọ