Kolose 1:14 BM

14 Nípasẹ̀ ọmọ rẹ̀ yìí ni a fi ní ìdáǹdè, àní ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ wa.

Ka pipe ipin Kolose 1

Wo Kolose 1:14 ni o tọ