Kolose 1:25 BM

25 Nítorí èyí ni mo ṣe di iranṣẹ láti mú ọ̀rọ̀ Ọlọrun ṣẹ, gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ tí Ọlọrun ti fún mi láti ṣe nítorí yín.

Ka pipe ipin Kolose 1

Wo Kolose 1:25 ni o tọ