Kolose 1:3 BM

3 À ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun, Baba Oluwa wa, Jesu Kristi, nígbà gbogbo tí a bá ń gbadura fun yín.

Ka pipe ipin Kolose 1

Wo Kolose 1:3 ni o tọ