Kolose 2:10 BM

10 Ó sì ti ṣe yín ní pípé ninu rẹ̀. Òun níí ṣe orí fún gbogbo àwọn ẹ̀mí ojú ọ̀run, ìbáà ṣe ìjọba tabi àwọn aláṣẹ.

Ka pipe ipin Kolose 2

Wo Kolose 2:10 ni o tọ