Kolose 3:23 BM

23 Ohunkohun tí ẹ bá ń ṣe, ẹ ṣe é tọkàntọkàn, bí ẹni pé Oluwa ni ẹ̀ ń ṣe é fún, kì í ṣe fún eniyan,

Ka pipe ipin Kolose 3

Wo Kolose 3:23 ni o tọ