Kolose 3:4 BM

4 Nígbà tí Kristi, ẹni tíí ṣe ẹ̀mí yín bá farahàn, ẹ̀yin náà yóo farahàn pẹlu rẹ̀ ninu ògo.

Ka pipe ipin Kolose 3

Wo Kolose 3:4 ni o tọ