2 Kí oore-ọ̀fẹ́ ati alaafia pọ̀ sí i fun yín nípa mímọ Ọlọrun ati Jesu Oluwa wa.
Ka pipe ipin Peteru Keji 1
Wo Peteru Keji 1:2 ni o tọ