Peteru Keji 2:2 BM

2 Ọpọlọpọ eniyan ni yóo bá wọn kẹ́gbẹ́ ninu ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ wọn; nítorí ìṣe wọn, àwọn eniyan yóo máa gan ọ̀nà òtítọ́.

Ka pipe ipin Peteru Keji 2

Wo Peteru Keji 2:2 ni o tọ