Peteru Kinni 1:10 BM

10 Àwọn wolii tí wọ́n ṣe ìkéde oore-ọ̀fẹ́ tún fẹ̀sọ̀ wádìí nípa ìgbàlà yìí.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 1

Wo Peteru Kinni 1:10 ni o tọ