2 Ẹ̀yin ni a yàn gẹ́gẹ́ bí ìmọ̀tẹ́lẹ̀ Ọlọrun Baba fún ìwà mímọ́ nípa Ẹ̀mí Mímọ́ kí ẹ lè máa gbọ́ ti Jesu Kristi, kí ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sì lè wẹ̀ yín mọ́.Kí oore-ọ̀fẹ́ ati alaafia kí ó pọ̀ fun yín.
Ka pipe ipin Peteru Kinni 1
Wo Peteru Kinni 1:2 ni o tọ