Peteru Kinni 2:25 BM

25 Nítorí pé nígbà kan ẹ dàbí aguntan tí ó sọnù. Ṣugbọn nisinsinyii ẹ ti yipada sí olùṣọ́ yín ati alabojuto ọkàn yín.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 2

Wo Peteru Kinni 2:25 ni o tọ