Peteru Kinni 3:14 BM

14 Ṣugbọn bí ẹ bá tilẹ̀ jìyà nítorí òdodo, ẹ ṣe oríire. Ẹ má bẹ̀rù àwọn tí wọn ń jẹ yín níyà, kí ẹ má jẹ́ kí ọkàn yín dàrú.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 3

Wo Peteru Kinni 3:14 ni o tọ