Peteru Kinni 3:18 BM

18 Nítorí Kristi kú lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo fún ẹ̀ṣẹ̀ wa; olódodo ni, ó kú fún alaiṣododo, kí ó lè mú wa wá sọ́dọ̀ Ọlọrun. A pa á ní ti ara, ṣugbọn ó wà láàyè ní ti ẹ̀mí.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 3

Wo Peteru Kinni 3:18 ni o tọ