13 Èyí sọ yín di alábàápín ninu ìjìyà Kristi. Ẹ máa yọ̀. Nígbà tí ó bá pada dé ninu ògo rẹ̀, ayọ̀ ńlá ni ẹ óo yọ̀.
Ka pipe ipin Peteru Kinni 4
Wo Peteru Kinni 4:13 ni o tọ