2 Má tún máa ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ẹ̀dá mọ́, ṣugbọn máa ṣe ìfẹ́ Ọlọrun ninu gbogbo ìgbé-ayé rẹ tí ó kù.
Ka pipe ipin Peteru Kinni 4
Wo Peteru Kinni 4:2 ni o tọ