1 Nítorí náà, mo bẹ àwọn àgbà láàrin yín, alàgbà ni èmi náà, ati ẹlẹ́rìí ìyà Kristi, n óo sì ní ìpín ninu ògo tí yóo farahàn.
Ka pipe ipin Peteru Kinni 5
Wo Peteru Kinni 5:1 ni o tọ